Láti inú ibú wá ni èmi ń ké pè é ọ́ OLúWA OLúWA, gbóhùn mi, jẹ́ kí etí rẹ kí o tẹ́ sílẹ̀ sí ohùn ẹ̀bẹ̀ mi. OLúWA, ìbá ṣe pé kí ìwọ máa sàmì ẹ̀ṣẹ̀, OLúWA, tá ni ìbá dúró. Nítorí ìdáríjì wà lọ́dọ̀ rẹ, kí a lè máa bẹ̀rù rẹ.
Kà Saamu 130
Feti si Saamu 130
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Saamu 130:1-4
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò