Ẹ fi ọpẹ́ fún OLúWA, nítorí tí ó dára; àánú rẹ̀ dúró láéláé. Jẹ́ kí Israẹli wí pé: “Àánú rẹ̀ dúró láéláé”. Jẹ́ kí ilé Aaroni wí pé: “Àánú rẹ̀ dúró láéláé”. Jẹ́ kí àwọn tí ó bẹ̀rù OLúWA wí pé: “Àánú rẹ̀ dúró láéláé.”
Kà Saamu 118
Feti si Saamu 118
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Saamu 118:1-4
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò