Òwe 14:3-4

Òwe 14:3-4 YCB

Ọ̀rọ̀ aṣiwèrè a máa ṣokùnfà pàṣán fún ẹ̀yìn rẹ̀, ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ ètè ọlọ́gbọ́n a máa dáàbò bò ó. Níbi tí kò sí ẹran, ibùjẹ ẹran a máa mọ́ tónítóní ṣùgbọ́n, nípa agbára akọ màlúù ni ọ̀pọ̀ ìkórè ti ń wá.