Jeremiah 23:5

Jeremiah 23:5 YCB

“Ọjọ́ ń bọ̀,” ni OLúWA wí, “tí Èmi yóò gbé ẹ̀ka òdodo dìde fún Dafidi, ọba tí yóò lo ìjọba pẹ̀lú ọgbọ́n tí yóò sì ṣe òdodo àti ohun tí ó yẹ lórí ilẹ̀ náà.