Jakọbu 1:20

Jakọbu 1:20 YCB

Nítorí ìbínú ènìyàn kì í ṣiṣẹ́ òdodo irú èyí tí Ọlọ́run ń fẹ́.