Isaiah 45:7

Isaiah 45:7 YCB

Mo dá ìmọ́lẹ̀, mo sì dá òkùnkùn mo mú àlàáfíà wá, mo sì dá àjálù; Èmi OLúWA ni ó ṣe nǹkan wọ̀nyí.