Hosea 11:12

Hosea 11:12 YCB

Efraimu tí fi irọ́ yí mi ká ilé Israẹli pẹ̀lú ẹ̀tàn. Ṣùgbọ́n Juda sì dúró ṣinṣin pẹ̀lú Ọlọ́run Ó sì ṣe olóòtítọ́ sí Ẹni mímọ́ Israẹli.