Habakuku 1:12

Habakuku 1:12 YCB

OLúWA, ǹjẹ́ láti ayérayé kọ ni ìwọ tí wà? OLúWA Ọlọ́run mi. Ẹni mímọ́ mi, àwa kì yóò kú OLúWA, ìwọ tí yàn wọn fún ìdájọ́; Ọlọ́run alágbára, ìwọ tí fi ẹsẹ̀ wọn múlẹ̀ fún ìbáwí