Gẹnẹsisi 30:24

Gẹnẹsisi 30:24 YCB

Ó sì pe orúkọ rẹ̀ ni Josẹfu, ó sì wí pé, “Ǹjẹ́ kí OLúWA kí ó fi ọmọkùnrin mìíràn kún un fún mi.”