Gẹnẹsisi 2:22

Gẹnẹsisi 2:22 YCB

OLúWA Ọlọ́run sì dá obìnrin láti inú egungun tí ó yọ ní ìhà ọkùnrin náà, Ó sì mu obìnrin náà tọ̀ ọ́ wá.