Ó bẹ̀rẹ̀ ìrìnàjò rẹ̀ láti Babeli ní ọjọ́ kìn-ín-ní oṣù kìn-ín-ní, ó sì dé Jerusalẹmu ní ọjọ́ kìn-ín-ní oṣù karùn-ún nítorí ọwọ́ àánú Ọlọ́run rẹ̀ wà ní ara rẹ̀. Esra ti fi ara rẹ̀ jì fún kíkọ́ àti pípa òfin OLúWA mọ́, ó sì ń kọ́ òfin àti ìlànà Mose ní Israẹli.
Kà Esra 7
Feti si Esra 7
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Esra 7:9-10
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò