A fi gbogbo nǹkan wọ̀nyí hàn yín kí ẹ bá a lè gbà pé OLúWA ni Ọlọ́run. Kò sì sí ẹlòmíràn lẹ́yìn rẹ̀. Ó jẹ́ kí ẹ gbọ́ ohùn rẹ̀ láti ọ̀run wá, láti kọ́ ọ yín. Ní ayé, ó fi iná ńlá rẹ̀ hàn yín, ẹ sì gbọ́ ohùn rẹ̀ láti àárín iná wá
Kà Deuteronomi 4
Feti si Deuteronomi 4
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Deuteronomi 4:35-36
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò