Nígbà náà ni mo pàṣẹ fún Joṣua pé, “Ìwọ tí fi ojú rẹ rí ohun gbogbo tí OLúWA Ọlọ́run rẹ tí ṣe sí àwọn ọba méjèèjì wọ̀nyí. Bẹ́ẹ̀ ni OLúWA yóò ṣe sí àwọn ilẹ̀ ọba tí ẹ̀yin n lọ. Ẹ má ṣe bẹ̀rù wọn, OLúWA Ọlọ́run yín tìkára rẹ̀ ni yóò jà fún un yín.”
Kà Deuteronomi 3
Feti si Deuteronomi 3
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Deuteronomi 3:21-22
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò