Nísinsin yìí ìwọ Israẹli, kín ni ohun tí OLúWA Ọlọ́run rẹ béèrè lọ́wọ́ rẹ? Bí kò ṣe kí ìwọ bẹ̀rù OLúWA Ọlọ́run rẹ àti láti máa rìn ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀, láti fẹ́ràn rẹ̀, láti fi gbogbo ọkàn rẹ sin OLúWA Ọlọ́run rẹ ọkàn àti àyà rẹ
Kà Deuteronomi 10
Feti si Deuteronomi 10
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Deuteronomi 10:12
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò