2 Samuẹli 12:13-14

2 Samuẹli 12:13-14 YCB

Dafidi sì wí fún Natani pé, “Èmi ṣẹ̀ sí OLúWA!” Natani sì wí fún Dafidi pé, “OLúWA pẹ̀lú sì ti mú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ kúrò; ìwọ kì yóò kú. Ṣùgbọ́n nítorí nípa ìwà yìí, ìwọ fi ààyè sílẹ̀ fún àwọn ọ̀tá OLúWA láti sọ ọ̀rọ̀-òdì, ọmọ náà tí a ó bí fún ọ, kíkú ní yóò kú.”