2 Kronika 1:3

2 Kronika 1:3 YCB

Pẹ̀lú Solomoni, àti gbogbo àpéjọ lọ sí ibi gíga ní Gibeoni, nítorí àgọ́ Ọlọ́run fún pípàdé wà níbẹ̀, tí Mose ìránṣẹ́ OLúWA ti pa ní aginjù.