1 Samuẹli 30:8

1 Samuẹli 30:8 YCB

Dafidi sì béèrè lọ́dọ̀ OLúWA wí pé, “Kí èmi ó lépa ogun yìí bi? Èmi lè bá wọn?” Ó sì dá a lóhùn pé, “Lépa: nítorí pé ni bíbá ìwọ yóò bá wọn, ni gbígbà ìwọ yóò sì rí wọn gbà.”