Nitorina li a si ṣe kà a si ododo fun u. A kò sá kọ ọ nitori tirẹ̀ nikan pe, a kà a si fun u, Ṣugbọn nitori tiwa pẹlu, ẹniti a o si kà a si fun, bi awa ba gbà a gbọ́, ẹniti o gbé Jesu Oluwa wa dide kuro ninu okú; Ẹniti a fi tọrẹ ẹ̀ṣẹ wa, ti a si jinde nitori idalare wa.
Kà Rom 4
Feti si Rom 4
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Rom 4:22-25
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò