O paṣẹ fun awọsanma lati òke wá, o si ṣi ilẹkùn ọrun silẹ. O si rọ̀jo Manna silẹ fun wọn ni jijẹ, o si fun wọn li ọkà ọrun. Enia jẹ onjẹ awọn angeli; o rán onjẹ si wọn li ajẹyo.
Kà O. Daf 78
Feti si O. Daf 78
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: O. Daf 78:23-25
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò