Iwọ sọ wa di ẹni-owe ninu awọn orilẹ-ède, ati imirisi ninu awọn enia. Idamu mi mbẹ niwaju mi nigbagbogbo, itiju mi si bò mi mọlẹ. Nitori ohùn ẹniti ngàn, ti o si nsọ̀rọ buburu; nitori ipa ti ọta olugbẹsan nì.
Kà O. Daf 44
Feti si O. Daf 44
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: O. Daf 44:14-16
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò