Ohùn Oluwa nyà ọwọ iná, Ohùn Oluwa nmì aginju; Oluwa nmì aginju Kadeṣi. Ohùn Oluwa li o nmu abo agbọnrin bi, o si fi igbo didi hàn: ati ninu tempili rẹ̀ li olukuluku nsọ̀rọ ogo rẹ̀.
Kà O. Daf 29
Feti si O. Daf 29
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: O. Daf 29:7-9
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò