O. Daf 131

131
Àṣírí ìfọ̀kànbalẹ̀
1OLUWA, aiya mi kò gbega, bẹ̃li oju mi kò gbé soke: bẹ̃li emi kò fi ọwọ mi le ọ̀ran nla, tabi le ohun ti o ga jù mi lọ.
2Nitõtọ emi mu ọkàn mi simi, mo si mu u dakẹjẹ, bi ọmọ ti a ti ọwọ iya rẹ̀ gbà li ẹnu ọmu: ọkàn mi ri bi ọmọ ti a já li ẹnu ọmu.
3Israeli, iwọ ni ireti lọdọ Oluwa lati isisiyi lọ ati lailai.

Àwon tá yàn lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí:

O. Daf 131: YBCV

Ìsàmì-sí

Pín

Daako

None

Ṣé o fẹ́ fi àwọn ohun pàtàkì pamọ́ sórí gbogbo àwọn ẹ̀rọ rẹ? Wọlé pẹ̀lú àkántì tuntun tàbí wọlé pẹ̀lú àkántì tí tẹ́lẹ̀