Emi o ti ma gbìmọ li ọkàn mi pẹ to? ti emi o ma ni ibinujẹ li ọkàn mi lojojumọ? ọta mi yio ti gberaga sori mi pẹ to? Rò o, ki o si gbohùn mi, Oluwa Ọlọrun mi: mu oju mi mọlẹ, ki emi ki o má ba sùn orun ikú. Ki ọta mi ki o má ba wipe, emi ti ṣẹgun rẹ̀; awọn ti nyọ mi lẹnu a si ma yọ̀, nigbati a ba ṣi mi nipò. Ṣugbọn emi o gbẹkẹle ãnu rẹ; ọkàn mi yio yọ̀ ni igbala rẹ.
Kà O. Daf 13
Feti si O. Daf 13
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: O. Daf 13:2-5
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò