O. Daf 119:1-16

Verse Images for O. Daf 119:1-16

O. Daf 119:1-16 - IBUKÚN ni fun awọn ẹniti o pé li ọ̀na na, ti nrìn ninu ofin Oluwa.
Ibukún ni fun awọn ti npa ẹri rẹ̀ mọ́, ti si nwá a kiri tinu-tinu gbogbo.
Nwọn kò dẹṣẹ pẹlu: nwọn nrìn li ọ̀na rẹ̀.
Iwọ ti paṣẹ fun wa lati pa ẹkọ́ rẹ mọ́ gidigidi.
Ọ̀na mi iba jẹ là silẹ lati ma pa ilana rẹ mọ́!
Nigbana li oju kì yio tì mi, nigbati emi ba njuba aṣẹ rẹ gbogbo.
Emi o ma fi aiya diduro-ṣinṣin yìn ọ, nigbati emi ba ti kọ́ idajọ ododo rẹ.
Emi o pa ilana rẹ mọ́: máṣe kọ̀ mi silẹ patapata.

Nipa ewo li ọdọmọkunrin yio fi mu ọ̀na rẹ̀ mọ́? nipa ikiyesi gẹgẹ bi ọ̀rọ rẹ.
Tinu-tinu mi gbogbo li emi fi ṣe afẹri rẹ: máṣe jẹ ki emi ṣina kuro ninu aṣẹ rẹ.
Ọ̀rọ rẹ ni mo pamọ́ li aiya mi, ki emi ki o má ba ṣẹ̀ si ọ.
Olubukún ni iwọ, Oluwa: kọ́ mi ni ilana rẹ.
Ẹnu mi li emi fi nsọ gbogbo idajọ ẹnu rẹ.
Emi ti nyọ̀ li ọ̀na ẹri rẹ, bi lori oniruru ọrọ̀.
Emi o ma ṣe àṣaro ninu ẹkọ́ rẹ emi o si ma juba ọ̀na rẹ.
Emi o ma ṣe inu-didùn ninu ilana rẹ: emi kì yio gbagbe ọ̀rọ rẹ.O. Daf 119:1-16 - IBUKÚN ni fun awọn ẹniti o pé li ọ̀na na, ti nrìn ninu ofin Oluwa.
Ibukún ni fun awọn ti npa ẹri rẹ̀ mọ́, ti si nwá a kiri tinu-tinu gbogbo.
Nwọn kò dẹṣẹ pẹlu: nwọn nrìn li ọ̀na rẹ̀.
Iwọ ti paṣẹ fun wa lati pa ẹkọ́ rẹ mọ́ gidigidi.
Ọ̀na mi iba jẹ là silẹ lati ma pa ilana rẹ mọ́!
Nigbana li oju kì yio tì mi, nigbati emi ba njuba aṣẹ rẹ gbogbo.
Emi o ma fi aiya diduro-ṣinṣin yìn ọ, nigbati emi ba ti kọ́ idajọ ododo rẹ.
Emi o pa ilana rẹ mọ́: máṣe kọ̀ mi silẹ patapata.

Nipa ewo li ọdọmọkunrin yio fi mu ọ̀na rẹ̀ mọ́? nipa ikiyesi gẹgẹ bi ọ̀rọ rẹ.
Tinu-tinu mi gbogbo li emi fi ṣe afẹri rẹ: máṣe jẹ ki emi ṣina kuro ninu aṣẹ rẹ.
Ọ̀rọ rẹ ni mo pamọ́ li aiya mi, ki emi ki o má ba ṣẹ̀ si ọ.
Olubukún ni iwọ, Oluwa: kọ́ mi ni ilana rẹ.
Ẹnu mi li emi fi nsọ gbogbo idajọ ẹnu rẹ.
Emi ti nyọ̀ li ọ̀na ẹri rẹ, bi lori oniruru ọrọ̀.
Emi o ma ṣe àṣaro ninu ẹkọ́ rẹ emi o si ma juba ọ̀na rẹ.
Emi o ma ṣe inu-didùn ninu ilana rẹ: emi kì yio gbagbe ọ̀rọ rẹ.

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú O. Daf 119:1-16