Oluwa ga lori gbogbo orilẹ-ède, ogo rẹ̀ si wà lori ọrun. Tali o dabi Oluwa Ọlọrun wa, ti o ngbe ibi giga. Ẹniti o rẹ̀ ara rẹ̀ silẹ lati wò ohun ti o wà li ọrun ati li aiye!
Kà O. Daf 113
Feti si O. Daf 113
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: O. Daf 113:4-6
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò