Mat 22:38-40
Mat 22:38-40 YBCV
Eyi li ekini ati ofin nla. Ekeji si dabi rẹ̀, Iwọ fẹ ọmọnikeji rẹ bi ara rẹ. Ninu awọn ofin mejeji yi ni gbogbo ofin ati wolĩ rọ̀ mọ́.