Mat 19:13

Mat 19:13 YBCV

Nigbana li a gbé awọn ọmọ-ọwọ wá sọdọ rẹ̀ ki o le fi ọwọ́ le wọn, ki o si gbadura: awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ si ba wọn wi.

Àwọn fídíò fún Mat 19:13