Lẹhin ikolọ si Babiloni ni Jekoniah bí Sealtieli; Sealtieli si bí Serubabeli; Serubabeli si bí Abiudu; Abiudu si bí Eliakimu; Eliakimu si bí Asoru; Asoru si bí Sadoku; Sadoku si bí Akimu; Akimu si bí Eliudu; Eliudu si bí Eleasa; Eleasa si bí Matani; Matani si bí Jakọbu; Jakọbu si bí Josefu ọkọ Maria, lati ọdọ ẹniti a bí Jesu, ti a npè ni Kristi.
Kà Mat 1
Feti si Mat 1
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Mat 1:12-16
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò