Ẹk. Jer 3:40-41
Ẹk. Jer 3:40-41 YBCV
Jẹ ki a wádi, ki a si dán ọ̀na wa wò, ki a si tun yipada si Oluwa. Jẹ ki a gbe ọkàn ati ọwọ wa soke si Ọlọrun li ọrun.