Nigbati mo jade là arin ilu lọ si ẹnu ibode, nigbati mo tẹ ìtẹ mi ni igboro. Nigbana ni awọn ọdọmọkunrin ri mi, nwọn si sapamọ́, awọn àgba dide duro. Awọn ọmọ-alade dakẹ ọ̀rọ sisọ, nwọn a si fi ọwọ wọn le ẹnu. Awọn ọlọla dakẹ, ahọn wọn si lẹmọ èrigi ẹnu wọn. Nitoripe eti gbọ́ ti emi, a si sure fun mi, oju si ri mi, on a jẹri mi. Nitoriti mo gba talaka ti nsọkun, ati alainibaba, ati alaini oluranlọwọ.
Kà Job 29
Feti si Job 29
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Job 29:7-12
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò