Joh 19:1-3

Joh 19:1-3 YBCV

NITORINA ni Pilatu mu Jesu, o si nà á. Awọn ọmọ-ogun si hun ade ẹgún, nwọn si fi de e li ori, nwọn si fi aṣọ igunwà elesè àluko wọ̀ ọ. Nwọn si wipe, Kabiyesi, Ọba awọn Ju! nwọn si fi ọwọ́ wọn gbá a loju.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ