Joh 12:49

Joh 12:49 YBCV

Nitori emi kò dá ọrọ sọ fun ara mi, ṣugbọn Baba ti o rán mi, on li o ti fun mi li aṣẹ, ohun ti emi o sọ, ati eyiti emi o wi.

Àwọn fídíò fún Joh 12:49