Abramu si wipe, OLUWA Ọlọrun, kini iwọ o fi fun mi, emi sa nlọ li ailọmọ, Elieseri ti Damasku yi si ni ẹniti o ni ile mi? Abramu si wipe, Wo o emi ni iwọ kò fi irú-ọmọ fun: si wo o, ẹrú ti a bi ni ile mi ni yio jẹ arolé. Si wo o, ọ̀rọ OLUWA tọ̀ ọ wá, wipe, Eleyi ki yio ṣe arole rẹ; bikoṣe ẹniti yio ti inu ara rẹ jade, on ni yio ṣe arole rẹ. O si mu u jade wá si gbangba, o si wi pe, Gboju wò oke ọrun nisisiyi, ki o si kà irawọ bi iwọ ba le kà wọn: o si wi fun u pe, Bẹ̃ni irú-ọmọ rẹ yio ri. O si gba OLUWA gbọ́; on si kà a si fun u li ododo.
Kà Gẹn 15
Feti si Gẹn 15
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Gẹn 15:2-6
5 Awọn ọjọ
Gbigbe irin ajo lọ si ohun ti a npe ni igbagbọ ti Bibeli A wo ìgbésí ayé Ábúráhámù, baba ńlá ìgbàgbọ́ nínú Bíbélì, àti díẹ̀ lára àwọn ìjíròrò rẹ̀ pẹ̀lú Ọlọ́ run, àwọn ìtọ́ ni wo ló ní láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́ run tí ó sì ṣègbọràn sí ohun tí Ọlọ́ run béèrè lọ́ wọ́ rẹ̀? Ti kii ba ṣe bẹ, awọn abajade odi wa fun iyapa rẹ?
7 Days
There are times we have a promise from God, but we don’t see our life lining up with the promise God has given us. Or there are times we reach a crossroads in our life, relying on God to speak direction into our lives, and we only hear silence. This 7-day devotional will speak to your heart about how to move in God’s Will when God seems to be quiet.
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò