Ati bi o ti ṣe si nyin li aginjù, titi ẹnyin fi dé ihin yi; Ati bi o ti ṣe si Datani ati Abiramu, awọn ọmọ Eliabu, ọmọ Reubeni; bi ilẹ ti yà ẹnu rẹ̀, ti o si gbe wọn mì, ati ara ile wọn, ati agọ́ wọn, ati ohun alãye gbogbo ti o tẹle wọn, lãrin gbogbo Israeli: Ṣugbọn oju nyin ti ri gbogbo iṣẹ nla OLUWA ti o ṣe.
Kà Deu 11
Feti si Deu 11
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Deu 11:5-7
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò