ÌFIHÀN 3:7

ÌFIHÀN 3:7 YCE

“Kọ ìwé yìí sí angẹli ìjọ Filadẹfia pé: “Ẹni mímọ́ ati olóòótọ́ nì, ẹni tí kọ́kọ́rọ́ Dafidi ń bẹ ní ọwọ́ rẹ̀, tíí ṣí ìlẹ̀kùn tí ẹnikẹ́ni kò lè tì í, tíí sìí tìlẹ̀kùn tí ẹnikẹ́ni kò lè ṣí i, ó ní