Jẹ́ kí pápá oko ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀ yọ̀. Nígbà náà ni gbogbo igi igbó yóo fi ayọ̀ kọrin, níwájú OLUWA, nítorí pé ó ń bọ̀; ó ń bọ̀ wá ṣe ìdájọ́ ayé. Yóo fi òdodo ṣe ìdájọ́ ayé; yóo sì fi òtítọ́ ṣe ìdájọ́ àwọn eniyan.
Kà ORIN DAFIDI 96
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ORIN DAFIDI 96:12-13
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò