ORIN DAFIDI 89:11

ORIN DAFIDI 89:11 YCE

Tìrẹ ni ọ̀run, tìrẹ sì ni ayé pẹlu; ìwọ ni o tẹ ayé ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀ dó.