ORIN DAFIDI 85:12

ORIN DAFIDI 85:12 YCE

Dájúdájú, OLUWA yóo fúnni ní ohun tí ó dára; ilẹ̀ wa yóo sì mú èso jáde lọpọlọpọ.