Ohùn OLUWA ń yọ iná lálá. Ohùn OLUWA ń mi aṣálẹ̀; OLUWA ń mi aṣálẹ̀ Kadeṣi. Ohùn OLUWA a máa mú abo àgbọ̀nrín bí, a máa wọ́ ewé lára igi oko; gbogbo eniyan ń kígbe ògo rẹ̀ ninu Tẹmpili rẹ̀.
Kà ORIN DAFIDI 29
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ORIN DAFIDI 29:7-9
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò