ORIN DAFIDI 28:2

ORIN DAFIDI 28:2 YCE

Gbọ́ ohùn ẹ̀bẹ̀ mi, bí mo ti ń kígbe sí ọ pé kí o ràn mí lọ́wọ́; tí mo gbé ọwọ́ mi sókè sí ìhà ilé mímọ́ rẹ.