Ninu ìṣòro ńlá ni mò ń ké pè ọ́, OLUWA! OLUWA, gbóhùn mi, dẹtí sí ohùn ẹ̀bẹ̀ mi. Bí OLUWA bá ń sàmì ẹ̀ṣẹ̀, ta ló lè yege? Ṣugbọn ní ìkáwọ́ rẹ ni ìdáríjì wà, kí á lè máa bẹ̀rù rẹ.
Kà ORIN DAFIDI 130
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ORIN DAFIDI 130:1-4
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò