Ṣùgbọ́n èmi gbẹ́kẹ̀lé ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀; n óo máa yọ̀ nítorí pé o óo gbà mí. N óo máa kọrin sí ọ, OLUWA, nítorí o ṣeun fún mi lọpọlọpọ.
Kà ORIN DAFIDI 13
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ORIN DAFIDI 13:5-6
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò