ORIN DAFIDI 119:63

ORIN DAFIDI 119:63 YCE

Ọ̀rẹ́ gbogbo àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ ni mí, àní, àwọn tí wọn ń pa òfin rẹ mọ́.