OLUWA, à ń bẹ̀ ọ́, gbà wá, OLUWA, à ń bẹ̀ ọ́, jẹ́ kí á ṣe àṣeyege. Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí ń bọ̀ wá ní orúkọ OLUWA, láti inú ilé rẹ ni a ti ń yìn ọ́, OLUWA.
Kà ORIN DAFIDI 118
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ORIN DAFIDI 118:25-26
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò