ORIN DAFIDI 102:2

ORIN DAFIDI 102:2 YCE

Má yọwọ́ lọ́ràn mi lọ́jọ́ ìṣòro! Dẹtí sí adura mi; kí o sì tètè dá mi lóhùn nígbà tí mo bá ké pè ọ́.