ÌWÉ ÒWE 3:33-35

ÌWÉ ÒWE 3:33-35 YCE

Ègún OLUWA wà lórí ìdílé ẹni ibi, ṣugbọn a máa bukun ibùgbé àwọn olódodo. A máa fi àwọn pẹ̀gànpẹ̀gàn ṣe ẹlẹ́yà, ṣugbọn a máa fi ojurere wo àwọn onírẹ̀lẹ̀. Ọlọ́gbọ́n yóo jogún iyì, ṣugbọn ojú yóo ti òmùgọ̀.