ÌWÉ ÒWE 17:12-13

ÌWÉ ÒWE 17:12-13 YCE

Ó sàn kí eniyan pàdé ẹranko beari tí a kó lọ́mọ, ju kí ó pàdé òmùgọ̀ ninu agọ̀ rẹ̀ lọ. Ẹni tí ó fibi san oore, ibi kò ní kúrò ninu ilé rẹ̀ lae.