ÌWÉ ÒWE 14:6

ÌWÉ ÒWE 14:6 YCE

Pẹ̀gànpẹ̀gàn a máa wá ọgbọ́n, sibẹ kò ní rí i, ṣugbọn ati ní ìmọ̀ kò ṣòro fún ẹni tí ó ní òye.