ÌWÉ ÒWE 14:3-4

ÌWÉ ÒWE 14:3-4 YCE

Ọ̀rọ̀ ẹnu òmùgọ̀ dàbí pàṣán ní ẹ̀yìn ara rẹ̀, ṣugbọn ọ̀rọ̀ ọlọ́gbọ́n a máa dáàbò bò ó. Níbi tí kò bá sí mààlúù tí ń tu ilẹ̀, kò lè sí oúnjẹ, ṣugbọn agbára ọpọlọpọ mààlúù níí mú ọpọlọpọ ìkórè wá.