Àwọn aládùúgbò talaka pàápàá kórìíra rẹ̀, ṣugbọn ọlọ́rọ̀ a máa ní ọpọlọpọ ọ̀rẹ́. Ẹni tí ó kẹ́gàn aládùúgbò rẹ̀ dẹ́ṣẹ̀, ṣugbọn ayọ̀ ń bẹ fun ẹni tí ó bá ṣàánú talaka.
Kà ÌWÉ ÒWE 14
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ÌWÉ ÒWE 14:20-21
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò